Choose Your Location:  

Support   

Contact Us

Bi a se le lo opo FLOWGUARD® CPVC

Wo Akopo Afihan ti ororun ti ilana ati le opo CPVC po pelu sanmanti olomi sooro mo arawon.

Wo bi ase le awon opo FlowGuard niirorun ti osi munadoko pelu sanmanti olomi sooro.

Wo bi ase n fi sanmanti olomi sooro le opo CPVC ninu awon afihan ntelentele yii.

  1. Ge opo na logboogba si bi o se fe ki o gun si.
  2. Nuu ibi enu opo na ti ori sakasaka kuro, dan enu opo na ki o mon, ki o si dami.
  3. Yo idoti kuro lara awon opo ti a fe le po.
  4. Fi sanmanti olomi sooro pa ita opo kini pelu inu opo keji ti a o kii bo.
  5. To awon opo wonyi jo.
  6. Je ki won gbe, ki o to ki won bo inu ara won.

Fun akopo alaye ti orinle nibiti ona lile opo FlowGuard Pipe ati Fittings ti a yan, e downloadi Ilana ti the FlowGuard CPVC Installation Guide.

Flowguard_Installation_Guide_Africa_Yoruba

FlowGuard Pipe and Fittings Installation Guide

Get the Installation Guide

Ready to Get Started?

Contact us for a free process suitability and technical consultation. We want to make sure you get the localized support and information you need to take your project from blueprint to completion.

Contact Us